Fatimah Awesu ti o jẹ iya Mojisola Awesu, akẹkọọ ile-ẹkọ Health Technology Offa ti wọn ba oku rẹ lori akitan ni Ilorin, ti pariwo si gbogbo aye ati ijọba ki wọn gba oun ki iya ma jẹ oun gbe. Fatimah ...
Gomina ipinlẹ Oyo, Seyi Makinde ti ṣapejuwe iya rẹ gẹgẹ bi obinrin to ni akinkanju, to ṣe gbẹkẹle, to ṣiṣẹ karakara nigba aye rẹ. Seyi Makinde lo sọ eyi lasiko to gbalejo Deji ti ilu Akure, to ṣe ...